Ṣé lóòótọ́ làwọn jàǹdùkú kò já ààfin Awujale gbà? Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ogun ṣàlàyé - BBC News Yorùbá
Ninu atẹjade kan ti agbẹnusọ ọlọpaa ọlọpaa Ogun, Oluseyi Babaseyi sọ pe awọn da ọlọpaa si aafin naa lati mojuto eto aabo nibẹ ni, ki wọn si ri daju pe ohun gbogbo n lọ letoleto.
Read more










